E Wo Nnkan Ti DAVIDO Se Fun CHIOMA Leyin Orin ASSURANCE

Ololufe ti Davido ko orin fun laipe yii pelu akole “ASSURANCE” ni a gbo wipe o ti tun ri nnkan miran gba lowo Davido. Oun ti Davido se fun yii je nnkan ti o n ya’ni lenu gidi gan-an ni o.

Arabinrin Chioma ti t’owo bo’we laipe yii lati bere Afihan Eto Ounje-sise. Ore-kunrin re so wipe ti won ko ba je ki owo ti won fe fi pee lati maa se eto naa ko ba po, awon ko le t’owo bo’we ti won si gba lati see.

Eni ti yoo se agbateru eto naa ni ogbeni DUNES.

A n fi asiko yii ki Chioma ku oriire naa. Ooya koni ya won o.

 

E wo awon aworan gbogbo bi o se lo:

chioma-bday-davido

chioma-bday-davido

 

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.