E WO Eni Ti BUHARI Gba Gegebii Agbenuso Re Fun IBO Odun 2019

Iyalenu ni oro naa je ni igba ti awon omo Nigeria gbo wipe Are Buhari fe pada si ipo Are nibi ibo Odun 2019 t’onbo lona. Leyin ti o ti kede ati dije ni o se afihan eni ti yoo maa gba enu re soro ki asiko ibo naa to-to, ni igba ibo naa ati leyin ibo naa.

Buhari yan Agbejoro Festus Keyamo ti aye mo kaakakiri fun ise nla ribi-ribi ti o ti se nipa jija fun eto omo eniyan ni orile ede Nigeria.

Festus ti gba Oye Agbejoro agba (Senior Advocate of Nigeria -SAN-) ni Orile ede yii, ti o si fi Iyansipo naa han ni ori ero alatagba Social Media ti twitter wipe won ti fi oun je agbenuso Are Buhari fun odun 2019.

Gegebi O ti ko ni ede geesi:

O wipe Oun yoo soro lori re ni kikun laipe.

Gege bi a ti mo, Ki buhari to lo si iri-ajo lo si ilu Oba (UK)ni ojo kesan osu kerin, o fi Edun okan re han wipe oun fe pada lo fun ipo Are ni Nigeria lodun 2019.

Ni igba ti Archbishop of Canterbury iyen Justin Welby ni ilu London pade Buhari, o beere idi ti o fi fe pada si ipo naa….

O wipe; Leyin ti awon omo Nigeria ti pariwo lori k’oun pada tabi ki oun ma pada…Oun pinnu lati fi edun okan oun han.

Buhari-breaking-festus-keyamo-appointed-as-spokesperson-for-2019-buhari-campaign-see-appointment-letter

 

Gege bi o se so ni ede Geesi:

“We have many things to focus on, like security, agriculture, economy, anti-corruption, and many others. We needed to concentrate on them, and politics should not be a distraction. The majority of Nigerians appreciate what we are doing, and that is why I am re-contesting.”

Are tesiwaju lati so awon ohun ribi-ribi ti ijoba re ti gbe se si alejo re ni ilu london paapajulo lori eto Ogbin (Agriculture) ni Orile ede Nigeria.

O wipe:

“We have cut the importation of rice by about 90%, saving billions of dollars in the process. People who rushed into petrol money have now gone back to agriculture. Even professionals have gone back to the land. Nigeria should be able to feed itself comfortably soon. I am so pleased,” the President said.

Lori wahala awon gbemo-gbemo ati Boko_Haram, o so wipe Kiko awon eniyan leko ni nnkan ti o kan lowo yii ki won le bo lowo etan ti o wa ninu esin ati asa. O tesiwaju wipe ko si esin kankan ti o gba pipa omolakeji lekun tabi ipaniyan laaye.

Alejo re ti o je ore re Justin Welby beere lowo re nipa Ija laarin awon daran-daran ati awon agbe ni orile ede Nigeria; Buhari daa lohun wipe Wahala naa dagba ju awon eniyan lo nitori wipe, ati ibere-pepe ni o ti wa ki eran maa damu nnkan ogbin sugbon laye ode oni, nnkan ti o je ki o buru ni pe, awon darandaran ohun ngbe ibon ati awon ohun ija oloro wa lati ja, won si wa lati ilu miran ni kii se Orile ede Nigeria ni awon fulani naa ti wa…Ko je bi Are ti so.

Ko da’nu duro nibe, o wipe awon daran-daran naa je eyi ti Muammar Gadaffi ti orile ede Libya ko ni ise sugbon leyin iku Gadafi ni won ti n sakiri ti won si n se ose kiri gbogbo orile ede ti won le de. Opo ninu won ni Buhari jeki a mo wipe awon pade ni igba ti won n koju awon omo-iko Boko Haram.

Buhari ka’gba oro naa nile wipe wahala naa kiise Ija-esin sugbon wahala Adugbo ati eto isuna ni orile ede Nigeria ti awon si n sise takun-takun lati daduro laipe ti oun yoo si fi eyin awon ti o wa nidi oro naa ti agba.

 

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

 • iroyinNiSoki  GB NNKAN TI AWN ENIYAN FI BU
  2 hours ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  - Ẹ GBỌ NNKAN TI AWỌN ENIYAN FI BU FAYỌṢE LẸYIN TI OLUDIJE RẸ FI'DIRẸMI Awọn Eniyan lori ẹrọ alatagba ti f'ọrọ nu Ọgbẹni Ayọdele Fayọṣe lori bi oludije rẹ ṣe fi'dirẹmi nibi IBO FUN IPO GOMINA ni ipinlẹ Ekiti. - Ọgbẹni John Kayode Fayẹmi ti o jẹ Oludije fun ẹgbẹ All Progressives Congress, APC ni o ja'we olubori ni ibi Ibo ti o kọja. Fayẹmi fi Ijọba ibilẹ Mejila (12) ju ọgbẹni Professor Olushọla Eleka lọ laarin Ijọba ibilẹ Mẹẹdogun (16) ti wọn ni ni Ipinlẹ EKITI.
 • IroyinNiSoki DOKITA KAYDE FAYMI TI JAWE OLUBORI NIBI IBO
  18 hours ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  . DOKITA KAYỌDE FAYẸMI TI JA'WE OLUBORI NIBI IBO GOMINA NI IPINLẸ EKITI PẸLU IBO LATI IJỌBA IBILẸ MEJILA . Ọgbẹni Profesọ Kọlapọ Oluṣọla labẹ Asia ẹgbẹ oṣelu PDP ni fayẹmi f'ọwọrọ ṣẹyin nibi ibo naa ti o gba iye Ijọba ibilẹ mẹrin pere. . Bẹẹni awọn oludije t'oku ri ibo diẹdiẹ jajẹ.
 • OjoibiLoriOrisun Inu wa dun notiripe e rojo oni !! Inu
  6 days ago by orisuntv  #OjoibiLoriOrisun  Inu wa dun notiripe e r'ojo oni !! Inu wa dun nitoripe e le odun kan ! Igba odun, Odun kan ni ooo!!  #EkuOjoIBI   @jaiye_monje   #OrisunTv 
 • IroyinNiSoki GB PDP TI PARIWO SITA WIPE KI BUHARI
  1 week ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  - ẸGBẸ PDP TI PARIWO SITA WIPE KI BUHARI KA ORUKỌ AWỌN TI O KO OWO NIGERIA JẸ ooooo - Awọn Ẹgbẹ PDP ti ke si Buhari lati ka orukọ awọn ti wọn ti ri owo Nigeria gba pada lọwọ wọn sita k'aye gbọ!! - Ẹkunrẹrẹ IROYIN naa yoo wa lori WWW.ORISUN.TV laipẹ yii - Ẹku ifẹ si Ikanni yii o
 • OjumoIre KINI ITUM OWE YII? A KO GBD
  1 week ago by orisuntv  #OjumoIre  - KINI ITUMỌ OWE YII? - A KO GBỌDỌ FINI J'OYE AWODI KO MA LEE GBE ADIYẸ >>>>
 • OrisunPosts GAARI ATI PA ATI SUGA Nj Ounj YORUBA
  1 week ago by orisuntv  #OrisunPosts  - GAARI ATI ẸPA ATI SUGA... Njẹ Ounjẹ YORUBA ni Eyi?
 • IroyinNiSoki  BA MURPHY AFOLABI DUP ooo O TI
  2 weeks ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  - Ẹ BA MURPHY AFOLABI DUPẸ ooo. O TI JA ỌKỌ TUNTUN.. - ELEDUMARE TI O ṢE TIẸ A ṢE TIYIN oooo( NB'AMIN)
 • IroyinNiSoki IJAMBA INA oooooo!! Oluwa gbawa ooo
  3 weeks ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  - IJAMBA INA oooooo!! - Oluwa gbawa ooo
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • IroyinNiSoki IYE OWO POST JAMB KO GBD PJU oooo
  3 weeks ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  - IYE OWO POST JAMB KO GBỌDỌ PỌJU oooo.... Ajo t'on bojuto eto ẹkọ lo sọ bẹẹ - Minisita fun eto Ẹkọ ni Orilẹ ede Nigeria Ọgbẹni Adamu Adamu ni o fi ọrọ yii mulẹ nibi ipade lori Eto Post Jamb ti ọdun yii... - Gẹgẹ bi Minisita naa ṣe ṣọ, Iye owo-iforukọsilẹ naa ko gbọdọ ju N2,000 lọ. - O sọ wipe l'ọdun t'okọja, ofin naa ko mulẹ sugbọn lọdun yii..... Awọn yoo Duro lati fidi rẹ mulẹ
 • TANI DAM NINU AWN TI O WA NINU AWORAN
  3 weeks ago by orisuntv TANI Ẹ DAMỌ NINU AWỌN TI O WA NINU AWORAN YII??
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • OjoIbiLoriOrisun Inu wa dun lati ki yin ku oriire oni
  3 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Inu wa dun lati ki yin ku oriire oni  @officialomobanke_  Lagbara Eedua, Odun tun-tun yii a gbe Aanu pade yin ni gbogbo Ona. Eku Ojo Ibi.  #OrisunTV   #OmoBanke 
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • IMUSE LATI OWO thesolaallyson TI JADE OOOO
  3 weeks ago by orisuntv IMUSE LATI OWO  @thesolaallyson  TI JADE OOOO
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • NigezieNews Oluwa oooooo!! Iku omo kii se nnkan to
  3 weeks ago by orisuntv  #NigezieNews  - Oluwa oooooo!! Iku omo kii se nnkan to kekere O! Ki Olorun bawa tu D Banj ati awon ebi re ninu oo
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.