Owo Palaba Babalawo Awon BADOO Ti Segi Ooo

Ni ilu Nigeria ni a ti gbo wipe owo awon olopa ti te ogbeni kan ti won n pe ni Fatai Adebayo; eyi ti won so wipe o maa n s’oogun fun awon Igara-olosa ati agbenipa Badoo t’on pa omode ati agbalagba ni agbegbe Ikorodu.

Ogbeni Adebayo ti awon ara ilu re mo si Alese bo si owo awon olopa ni idi oosa re ni Ilu IMOSAN ti o wa ni Ijebu-Ode ti ipinle Ogun.

Ileese pepa gbe iroyin naa ni aaro yii gegebi iroyin ti a ri gbo. Atejade inu iwe iroyin naa so wipe Oga olopa CHike Oti ti o je Olukede fun awon olopa ni ilu Eko (Lagos State Police Public Relations Officer -PPRO) ni o mu otito nipa isele naa ja si owo awon Oniroyin.

Awon eniibi badoo ti won ti rimu tele ni won mu awon olopa lo si ilu Imosan lati lo mu Baba-alawo naa.

Awon T’O n Ta Epo Petrol Ti Pariwo Wipe Awon Ko Le Ta Epo Ni 145 MO

Gege bii nnkan ti Awon olopa so, awon omo egbe Badoo naa kii lo pa’niyan lai bere akosejaye enikeni ti won ba fe pa; ti won si maa n s’oogun lati loore ati boore. Iroyin naa tun jade wipe olori awon agbenipa naa fe fese fee/na papa bora, o fe gba ori omi salo sugbon owo tee.

Gege bi won ti so ni ede oyinbo;

Shrine-Fatai-Adebayo-Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan

“Adebayo, 34, who specialises in administering oath on members of the group before they launch any attack, was arrested at his shrine located in Imosan village, a suburb of Ijebu-Ode, Ogun State.

“The arrest of the herbalist followed the arrest of some Badoo cult suspects at the weekend, including the overall head of the group.

“Speaking while parading Adebayo before newsmen at the shrine, the State’s Commissioner of Police, Mr. Imohimi Edgal, said the head of the group was arrested on water during an attempt to escape.

“The CP, who led the operation involving the Commander of Rapid Response Squad, ACP Tunji Disu; Chairman of Lagos State Special Task Force, SP Yinka Egbeyemi, among others, said investigation was still ongoing but that the full details about the arrests made so far would be disclosed on Thursday at a press briefing,” the statement revealed.

Awon olopa wo ile oosa baba-alawo naa bi won ti fiye awon ara-Ikorodu wipe awon yoo mojuto aye ati dukia awon ti o n gbe ilu Ikorodu naa eyi ti o je oro ti awon ti o n gbe agbegbe naa ti n duro de lati enu awon olopa.

Ogbeni Oti tesiwaju ni ede geesi wipe;

Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan

Owo Olopa Te Onisenlaabi Ti O Wa Nidi Ajaale Ilu Sango Ota

“Revealing how the herbalist was arrested, Edgal said, ‘One of the suspects arrested confessed and he led us here that before they go for any killing, the head of the group brings them to this gentleman (Adebayo) to come and carry out oath for both themselves and the piece of stone they used for their killings and that they don’t go for any killing without first of all coming for oath in this shrine and that is why we are here.

“This gentleman is an accomplice before the fact and so definitely we are placing him under arrest and as well as sealing off the shrine till after investigation.

“I will give further details on Thursday during my press briefing but I can assure the good people of Ikorodu, Lagosians and Nigerians that we will not rest until this evil is completely rooted out from Lagos State.

“The CP also made a brief stop-over at the palace of the traditional ruler of Imosan Village, Chief Tajudeen Muili to intimate him of the criminal activities going on in his domain.

“At the shrine located at No 38, Ayegbami Quarters in Imosan, which was later demolished by policemen, there were different charms and big stones said to be used for the illicit activities of the Badoo group,” the police mentioned in addition to an earlier statement.

Ki Isele yii to se, ni ojo keji si oduntuntun ti a wo yii ni a gbo wipe awon Badoo pa idile kan ni agbegbe Ibeshe ni ipinle ogun. Gege bii iwadi wa, Ogbeni Shakiru ni olori idile naa ti won riidaju wipe won pa ki won to kuro nibe. Eyi ko awon olopa l’ominu nitori wipe o tako idaniloju ti awon olopa filele wipe awon yoo bojuto dukia ati emi awon ara ilu.

E WO FIDIO TI O WA LOKE YII KI E LE WO BI O TI SELE. ⇑⇑

Shrine-Fatai-Adebayo-Baddo-Badoo-Killers-ritualists-ritualist-ikorodu-ibeshe-ogun-state-imosan

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

 • OjoIbiLoriOrisun Elede A Doyo Ariwo re lo maa po nihellip
  18 hours ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Elede A D'oyo, Ariwo re lo maa po ni Owe awon agba ti o soro nipa aforiti..Bi e ti foriti gbogbo adun ati ikoro inu ise orin ni o bi igbadun ti o n waye nisin yii. Loni Ojo Ibi yin,A n gbaa l'adura wipe Aye yin Ko ni mo IKORO mo laye. Emi yin a se pupo re laye  @9iceofficial 
 • iroyinLoriOrisun Bi o e l ni Ilu y Atiba nihellip
  3 days ago by orisuntv  #iroyinLoriOrisun  Bi o ṣe lọ ni Ilu Ọyọ Atiba ni ibi ti wọn ti fi Ọgbẹni GANI ADAMS jẹ ARẸ ỌNA KAKANFO ilẹ YORUBA.. Ẹ sun Aworan yii ṣẹgbẹ... Awọn aworan miran wa ni WWW.ORISUN.TV
 • iroyinNiSoki gbni ti o j Olukaroyin ni ori Tlifisan Ijbahellip
  3 days ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  Ọgbẹni ti o jẹ Olukaroyin ni ori Tẹlifisan Ijọba NTA CYRIL STOBER gbe akẹgbẹ rẹ Elizabeth Banu ni Iyawo ni Ilu Adamawa ni agbegbe YOLA ... Awọn mejeeji ti n barawọn sọrẹ fun Ọdun diẹ ki wọn to gbe igbesẹ yii... A gbaa l'adura wipe Ọlọrun yio f'ere si Igbeyawo wọn.. (Amin)
 • IroyinNiSoki Ar Muhammadu Buhari ti parwa si awn ti ohellip
  3 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Arẹ Muhammadu Buhari ti parọwa si awọn ti o wa lori ẹrọ Ayelujara wipe ki wọn mọ nnkan ti wọn nkọ.... - Ninu ọrọ rẹ, ti o sọ ni Ede gẹẹsi o wipe: Evil doers and enemies of our country are obviously at work, seeking ways to further advance their pernicious acts. The message is denounced in its entirety, and President Buhari stands by his earlier condemnation of the killings in Benue and other parts of the country as dastardly and unacceptable before God and man. Those behind the concocted message are also enemies of God and man, who…
 • AkiiyinO Lagbara Olrun NI S TUNTUN TI A MUhellip
  1 week ago by orisuntv  #AkiiyinO  Lagbara Olọrun ... NI ỌSẸ TUNTUN TI A MU YII.... ẸRIN AYỌ YIO PA WA ooo
 • Related
  2 weeks ago by orisuntv Related
 • OrisunPosts LONI NI O PE DUN KAN TI IYA WAhellip
  2 weeks ago by orisuntv  #OrisunPosts  LONI NI O PE ỌDUN KAN TI IYA WA TI RE IRIN AJO-ARINMABỌ.... Ki Oluwa bawa tẹ wọn si afẹfẹ rere... RIP TOYIN MAJẸKODUNMI
 • IroyinNiSoki Eemo Tun Ti Wolu OoooAwon Agbenipa BADOO Tun Tihellip
  2 weeks ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Eemo Tun Ti Wolu Oooo..Awon Agbenipa BADOO Tun Ti Pada Wa Wahala tun ti be sile ni Ilu Eko oooooo. Bi won ti gbe iroyin wa si eti igbo wa wipe awon Agbenipa Baddo tun ti pada si ilu Ikorodu. Awon idile kan ni Ilu Ibeshe ni agbagbe Ikorodu ni ilu eko naa ni Isele nlaa’bi naa ti se; bi odindi Baba, omo ati iya omo naa ni awon agbenipa naa ran lo si orun are-mabo.
 • OjoIbiLoriOrisun MERCY AIGBE n pe m Ogoji j Loni Ahellip
  2 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  MERCY AIGBE n pe Ọmọ Ogoji Ọjọ Loni. A n baa yọ, a si n fi asiko yi dupẹ lọwọ Eedua Fun Isadi Ẹmi wọn... ẸKU IYEDUN!!
 • KU DUN Tuntun oooo IRE ATI AY NI A Ohellip
  2 weeks ago by orisuntv ẸKU ỌDUN Tuntun oooo IRE ATI AYỌ NI A O FI LAAJA.
 • OjoIbiLoriOrisun Loni ni Ayaj j Ibi JLILI femiadebayosalami ni tihellip
  3 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Loni ni Ayajọ Ọjọ Ibi JẸLILI  @femiadebayosalami  Ẹni ti o jẹ Oṣere ati Ogbountarigi ninu Ere oriitage. Bẹẹni o jẹ Oludamọran fun Gomina ipinlẹ Kwara.. Lagbara Eedua, Iṣẹ ko nii wọ iṣe yin. Gbogbo nnkan ti ẹ ba n dawọle yoo yọri si daadaa... Ẹku Ọdun, Ẹku Iyedun
 • MAMA PLU AKARA OYINBO J IBI WN cc solasobowale
  3 weeks ago by orisuntv MAMA PẸLU AKARA OYINBO ỌJỌ IBI WỌN cc  @solasobowale 
 • KINI E LE FIWE sanyri ninu aworan yiii??
  3 weeks ago by orisuntv KINI E LE FIWE sanyẹri ninu aworan yiii??
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • OjoIbiLoriOrisun la Sobowale j agba Oere nidi sinima Ogbountarigi ninuhellip
  3 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Ṣọla Sobowale jẹ agba Oṣere nidi sinima. Ogbountarigi ninu ere oriitage. Loni ni wọn n ṣe Ajọyọ Ọjọ ibi. Wọn n dupẹ lọwọ ọlọrun fun Ọdun miran lori ilẹ alaaye. Awa naa si n fi asiko yii bẹ Eedua wipe Ajinnde yoo maa jẹ tara wọn ooo. Ẹ wipe AṢẸẸẸẸẸẸ
 • OjoIbiLoriOrisun KI BIDUN KOWO KU ORIIRE oni ooooo Waahellip
  3 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Ẹ KI BIỌDUN ỌKẸOWO KU ORIIRE oni ooooo... Waa gbo, waa tọ, wa ṣoriire cc  @officialomobutty 
 • KU DUN ooooo mi gbogbo wa a e pup rhellip
  3 weeks ago by orisuntv ẸKU ỌDUN ooooo Ẹmi gbogbo wa a ṣe pupọ rẹ laye ati laaye wa ooooo
 • OjoIbiLoriOrisun Ork rere sn ju wr ti fdk l Inuhellip
  4 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Orúkọ rere sàn ju wúrà àti fàdákà lọ Inu wa dun lati ba eni ti O ni oruko rere ku oriire oni. Emi re a se pupo re laye oooo (Amin)  @iyaboojofespris 
 • E ki oluwabukolaarugba ku oriire Oni o Wipe Emi rehellip
  4 weeks ago by orisuntv E ki  @oluwabukola_arugba  ku oriire Oni o Wipe Emi re A se pupo re laye ati laaye re... Gbogbo wa ni Ileese Orisun n Kiiyin ku Ojo Ibi ooooo.
 • OwambeLoriOrisun ANKARA GIG TDUN YI MAA NGBA plu officiallizdasilva hellip
  4 weeks ago by orisuntv  #OwambeLoriOrisun  ANKARA GIG T'ỌDUN YI MAA NẸGBA pẹlu  @officiallizdasilva  ,  @ijebuu   @officiallolo1  ati bẹẹbẹẹlọ 24tj DECEMBER ni ooo

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.