Bi Fayemi Se Ja Ilu EKiti lole – IGBIMO IWADI

Iroyin ti o n de si eti igbo wa losan oni ni wipe Ajo Idajo Ati Iwadi ti ilu ekiti gbe kale lati seto lori inadura labe ijoba Kayode Fayemi ti o je gomina teleri ti pariwo sita wipe, Gomina teleri naa gbodo se awari iye owo N2.75 Billionu naira ti won yo ninu N25 billion ti won gba lowo ijoba apapo fun kiko Oja Nla ‘Ultra-Modern Market’ si ilu Ado-Ekiti ti won ko pada se.

Ajo ti o n se iwadi baa so fun agbases ti won gba lati tun Ibi ise ati ile ijoba (government house) ti Fayemu n gbe; ki o da iye Owo N324.8millionu naira bi won ti so wipe iye owo fun use baa ko ye ko ju bi N280 milionu naira lo.

IDI TI AWON ALASE CITY PEOPLE AWARDS SE PIN AYEYE WON KELEKELE

Igbimo fun iwadi naa ri asiri kan nipa KITWOOD NIGERIA LIMITED ti o gba ise itoju Ile Ijoba naa gba N600 iye millionu ti ko si ni adireesi kankan ti won si ti gbe owo naa fun-un, adireesi ti won fi sibi je ile ti won ko tii kole si eyi ti o wa ni agbegbe Central Bank ni ona Iyin ni ilu Ado Ekiti.

FAYEMI-PROBE-EFCC-COMMISION-FUNDS_CARS-EKITI

Asiri yii ati omiran ni o jade loni ojo’bo nigba ti Igbimo ti o n wadi naa gbe ejo naa lo s’odo Gomina tuntun; iyen Governor Ayodele Fayose ti Ogbeni Silas Oyewole si je Adari igbimo naa.

Igbimo naa so wipe, nigbati Ijoba Fayemi yoo ra Moto, Ileese Coscharis ni o gbe iye oko  ojilenigba din marun si òjìlénígba lé mewaa Oko ayokele ati boosi wipe o ja ijoba lole ti o si gbe wahala si agbada ijoba naa.

E Wo Nnkan Ti Ero AyarabiAsa Google Se Si Awon Orin Davido

Gebe bi won ti wi ni ede geesi;

“That Coscharis Motors supplied some vehicles outside Ekiti State especially, at Ibadan Liaison office when Ekiti State Government does not have a Liaison office in Ibadan. In respect of this, seven vehicles were supplied outside the State and signed for by unknown persons. 

“That Coscharis Motors only supplied 219 vehicles to the Ekiti State government and that 17 Joylong Buses were supplied to the Ekiti State Government as gift but later carted away.”

Awon nnkan miran wa ti ko tii tu sita bi won ti so fun awon oniroyin sugbon bi o ba se n jade ni o maa fi too yin leti.

 

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

 • Related
  2 days ago by orisuntv Related
 • YONBO ANABI
  6 days ago by orisuntv Ẹ YONBO ANABI _______
 • Related
  6 days ago by orisuntv Related
 • Related
  6 days ago by orisuntv Related
 • Related
  7 days ago by orisuntv Related
 • Related
  1 week ago by orisuntv Related
 • RamadanKareem Ramadhan 1439AH DAY 27 Its not too late
  1 week ago by orisuntv  #RamadanKareem  - Ramadhan 1439AH ✨DAY  #2 ⃣7⃣✨ *It's not too late to go for itikhaf* Al-Bukhaari narrated that ‘Umar ibn al-Khattaab (may Allaah be pleased with him) vowed to spend one night in i’tikaaf in al-Masjid al-Haraam, and the Prophet (peace and blessings of Allaah be upon him) told him to fulfil his vow. Reference: al-Bukhaari 2042 Muslim 1656 This hadith indicates that it is valid to observe *i'tikaaf for one night or day*. ✅So, if you still intend on reviving/practing this great Sunnah, its *never too late!!!* Pray: Our Lord! Bestow on us endurance and make our foothold sure and
 • KU J IBI oooo!! alagatoposh Igba dun dun kan ni
  2 weeks ago by orisuntv ẸKU ỌJỌ IBI oooo!!  @alagatoposh  Igba Ọdun. Ọdun kan ni o
 • Related
  2 weeks ago by orisuntv Related
 • iroyinNiSoki gbni ti n wo yii ti Ku
  2 weeks ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  - Ọgbẹni ti ẹ n wo yii ti Ku oooo.. Ni Igba Aye rẹ, O jẹ Ọga ni Ileeṣẹ PHCN. A gbọ wipe awọn eniyan kan ni wọn sọọ lokuta pa ni ilu Ọta ti ipinlẹ Ogun - Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa ni WWW.ORISUN.TV
 • Repost from kingbuilderlimited using RepostRegramApp SMART INVESTORS BOUGHT THE
  2 weeks ago by orisuntv Repost from  @kingbuilderlimited  using  @RepostRegramApp  - SMART INVESTORS BOUGHT THE OLD GRA IKEJA IN THE EARLY 70's SMARTER INVESTORS BOUGHT THE OLD VI AND IKOYI IN THE EARLY 80's SMARTEST INVESTORS BOUGHT THE PRESTIGIOUS LEKKI PHASE 1 IN THE MID 90's THOUGH IT WAS SAID TO BE "WATERLOGGED" TODAY, THEIR SMARTNESS HAS PAID OFF BECAUSE THEY ARE REAPING FROM THEIR INVESTMENTS THAT'S WORTH MORE THAN 5000% APPRECIATION. WHY DONT YOU JOIN THE SMART INVESTOR AND OWN A PLOT OF LAND AT ORISUN ESTATES EPE. FLEXIBLE PAYMENT PLAN ALSO AVAILABLE Contact Us today  @kingbuilderlimited   @kbhomeplan  to help you become a landlord
 • AworanLoriOrisun TANI E FERAN JU? A B C TABI
  2 weeks ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  - TANI E FERAN JU? A, B C TABI D?
 • OrisunNews iroyinLoriOrisun  gb nnkan ti gbni hehu Sani
  2 weeks ago by orisuntv  #OrisunNews   #iroyinLoriOrisun  - Ẹ gbọ nnkan ti Ọgbẹni Ṣhehu Sani sọ nipa awọn ti o n ṣe ijọba lọwọ-lọwọ - Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa ni WWW.ORISUN.TV -  #OrisunTV   #Ijoba   #Carpenter   #Frame   #Change 
 • iroyinNiSoki AKWE GB APC TI K IWE IFISIL oooo!!
  3 weeks ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  - AKỌWE ẸGBẸ APC TI KỌ IWE IFIṢẸSILẸ oooo!! - Senator Benjamin Uwajumogu, ti o jẹ akọwe fun National Convention Committee ri ẹgbẹ All Progressives Congress (APC), ti fun ẹgbẹ naa ni iwe ifiṣẹsilẹ - Ifiposilẹ naa waye gẹgẹ bii aba ti akọwe sinetọ naa Godson Amadikwa ti o wipe fifiṣẹsilẹ naa wa fun igbeleke ẹgbẹ naa ni ilu Imo a Ẹkunrẹrẹ lori Iroyin naa wa ni Ẹrọ Ayelujara wa gẹgẹbi Iṣe wa. -  #NEWS   #IMO   #lagos   #APC 
 • IroyinLoriOrisun gbni Small Doctor ni wn ti kede loni
  3 weeks ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  - Ọgbẹni Small Doctor ni wọn ti kede loni Ọjọ Ẹti wipe oun naa ti darapọ mọ awọn Aṣoju Ileeṣẹ naa - Ololufẹ ORISUN ati  @iam_smalldoctor , Ẹ Kii ku Oriire naa o!!
 • AworanLoriOrisun TANI O WA NINU AWORAN YII? KINI NNKAN
  3 weeks ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  - TANI O WA NINU AWORAN YII? KINI NNKAN TI Ẹ FẸRAN NIPA RẸ? KINI Ẹ KO FẸRAN NIPA RẸ? -  #Barbie   #Orisun   #OrisunTV 
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.