Aajo DSS Pe Dasuki Si Ile Ejo Fun Ijejo Olisa Metuh

Eka ti o n bojuto ise ipinle ti a n pe ni DSS ti gga si ase ti Ile Ejo Ijoba agba ti ilu abujo so bi won se pe fun Sambo Dasuki lati wa nibi Ijejo Olisa Metuh ti a fesun kan wipe o fa owo ijoba s’apo. Ogbeni Olisa Metuh je akapo fun National Publicity ti egbe PDP.

Metuh ti o n jejo fun Esun lilo owo ijoba fun imo t’ara eni nikan pe fun ifarahan Dasuki gege bii eleri lati daso asiri boo ni Ile Ejo. Ajo DSS naa ko mu ogbeni Dasuki wa si ile Ejo ni ijoko keyin ti won se ni ile ejo. Dasuki si be’be ni aaro yii pelu awon omo Ogun DSS naa.

Metuh who is being tried for alleged money laundering, had requested for Dasuki’s appearance as a witness to defend him in the case.  The DSS had failed to produce the former NSA at the previous sitting.  Dasuki arrived at the court this morning in the company of DSS operatives.

TeeMirror

View all posts

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.