Nnkan Meta Ti O Ye Ki A Fi Akiyesi Si Nibi Boolu Ti Nigeria Gba Pelu Argentina

Awon idije meji seyin ti o waye laarin Algeria pelu Argentina ti fun wan ni eri wipe Iko Super Eagles kii se omode mo. O tun je ki a mo ipo ti awon agbaboolu kookan wa bi won ti n gbe asia ile wa lo si Russia 2018.

Orisun ti se agbeyewo ohun marun ti a ri ko leko nibi Idije fun eni ti yoo gba boolu agbaye ‘World Cup’ ti o waye laarin Nigeria ati Argentina pelu bi won ti jawe olubori nibi ifesewonse naa.

Nigeria-vs-argentina-Russia-2018-NIGEZIE-SPORT

1)

Lakoko, Daniel Akpeyi ko tii dara to. Beeni Uzoho ye ki o ni anfani lati tele won lo si Russia 2018 nitoripe Daniel Akpeyi ko tii koju osuwon. Wahala ni o da sile nibi ese akoko ti won gba ti o si faa ki won gba ami ayo kan wole. Ni’dakeji, Francis Uzoho je eni ti o dena de boolu ti Benedetto d’ori gba lowo ipari ere boolu naa.

E TUN LE KA: Agbaboolu Kenneth Omeruo De Nu Igbeyawo ko Afesona Re

2)

Leekeji, Gernot Rohr je Akonimoogba ti o lopolo; nigbati awon ti won to lati wole laarin agbaboolu Super Eagles fi formation 3-5-2 lele, opo eniyan ni enu ya. Orile ede ti o po ni ko ni lo iru eto yii lati fi gba boolu sugbon ogbeni Rohr mo nnkan ti o n se ti o fi pa eto 4-3-3 sile. O mo wipe akonimoogba Argentina; ogbeni Jorge Sampaoli yoo gbe awon agbaboolu t’opo sori oun.

Idi niyen ti o fi lo Eto 3-5-2.

Nigeria-vs-Argentina-Nigeria-vs-argentina-Russia-2018-NIGEZIE-SPORT-SUPER_EAGLES

3)

Lekeeta, Opolopo agbaboolu ti o loruko ni ko gba boolu lojo naa. Awon bii

Ogenyi Onazi, Odion Ighalo, Mikel Agu, Elderson Echiejile ati Moses Simon. Nje bi apakeji Ere boolu naa ti de ni Rohr gbe awon ti o gbe ogo Super Eagles lojo naa wole. Awon bii Tyronne Ebuechi, Ahmed Musa, Brian Idowu pelu Kenneth Omeruo.

Eyi fihan wa wipe Wura ni Iko egbe agbaboolu Super Eagles je si orile ede Nigeria bi won ti muwa lo si Idije nla naa Russia 2018.

Nigeria-vs-Argentina-Nigeria-vs-argentina-Russia-2018-NIGEZIE-SPORT-SUPER_EAGLES

2 comments

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

 • YONBO ANABI
  3 days ago by orisuntv Ẹ YONBO ANABI _______
 • Related
  3 days ago by orisuntv Related
 • Related
  3 days ago by orisuntv Related
 • Related
  4 days ago by orisuntv Related
 • Related
  6 days ago by orisuntv Related
 • RamadanKareem Ramadhan 1439AH DAY 27 Its not too late
  6 days ago by orisuntv  #RamadanKareem  - Ramadhan 1439AH ✨DAY  #2 ⃣7⃣✨ *It's not too late to go for itikhaf* Al-Bukhaari narrated that ‘Umar ibn al-Khattaab (may Allaah be pleased with him) vowed to spend one night in i’tikaaf in al-Masjid al-Haraam, and the Prophet (peace and blessings of Allaah be upon him) told him to fulfil his vow. Reference: al-Bukhaari 2042 Muslim 1656 This hadith indicates that it is valid to observe *i'tikaaf for one night or day*. ✅So, if you still intend on reviving/practing this great Sunnah, its *never too late!!!* Pray: Our Lord! Bestow on us endurance and make our foothold sure and
 • KU J IBI oooo!! alagatoposh Igba dun dun kan ni
  1 week ago by orisuntv ẸKU ỌJỌ IBI oooo!!  @alagatoposh  Igba Ọdun. Ọdun kan ni o
 • Related
  2 weeks ago by orisuntv Related
 • iroyinNiSoki gbni ti n wo yii ti Ku
  2 weeks ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  - Ọgbẹni ti ẹ n wo yii ti Ku oooo.. Ni Igba Aye rẹ, O jẹ Ọga ni Ileeṣẹ PHCN. A gbọ wipe awọn eniyan kan ni wọn sọọ lokuta pa ni ilu Ọta ti ipinlẹ Ogun - Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa ni WWW.ORISUN.TV
 • Repost from kingbuilderlimited using RepostRegramApp SMART INVESTORS BOUGHT THE
  2 weeks ago by orisuntv Repost from  @kingbuilderlimited  using  @RepostRegramApp  - SMART INVESTORS BOUGHT THE OLD GRA IKEJA IN THE EARLY 70's SMARTER INVESTORS BOUGHT THE OLD VI AND IKOYI IN THE EARLY 80's SMARTEST INVESTORS BOUGHT THE PRESTIGIOUS LEKKI PHASE 1 IN THE MID 90's THOUGH IT WAS SAID TO BE "WATERLOGGED" TODAY, THEIR SMARTNESS HAS PAID OFF BECAUSE THEY ARE REAPING FROM THEIR INVESTMENTS THAT'S WORTH MORE THAN 5000% APPRECIATION. WHY DONT YOU JOIN THE SMART INVESTOR AND OWN A PLOT OF LAND AT ORISUN ESTATES EPE. FLEXIBLE PAYMENT PLAN ALSO AVAILABLE Contact Us today  @kingbuilderlimited   @kbhomeplan  to help you become a landlord
 • AworanLoriOrisun TANI E FERAN JU? A B C TABI
  2 weeks ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  - TANI E FERAN JU? A, B C TABI D?
 • OrisunNews iroyinLoriOrisun  gb nnkan ti gbni hehu Sani
  2 weeks ago by orisuntv  #OrisunNews   #iroyinLoriOrisun  - Ẹ gbọ nnkan ti Ọgbẹni Ṣhehu Sani sọ nipa awọn ti o n ṣe ijọba lọwọ-lọwọ - Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa ni WWW.ORISUN.TV -  #OrisunTV   #Ijoba   #Carpenter   #Frame   #Change 
 • iroyinNiSoki AKWE GB APC TI K IWE IFISIL oooo!!
  2 weeks ago by orisuntv  #iroyinNiSoki  - AKỌWE ẸGBẸ APC TI KỌ IWE IFIṢẸSILẸ oooo!! - Senator Benjamin Uwajumogu, ti o jẹ akọwe fun National Convention Committee ri ẹgbẹ All Progressives Congress (APC), ti fun ẹgbẹ naa ni iwe ifiṣẹsilẹ - Ifiposilẹ naa waye gẹgẹ bii aba ti akọwe sinetọ naa Godson Amadikwa ti o wipe fifiṣẹsilẹ naa wa fun igbeleke ẹgbẹ naa ni ilu Imo a Ẹkunrẹrẹ lori Iroyin naa wa ni Ẹrọ Ayelujara wa gẹgẹbi Iṣe wa. -  #NEWS   #IMO   #lagos   #APC 
 • IroyinLoriOrisun gbni Small Doctor ni wn ti kede loni
  2 weeks ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  - Ọgbẹni Small Doctor ni wọn ti kede loni Ọjọ Ẹti wipe oun naa ti darapọ mọ awọn Aṣoju Ileeṣẹ naa - Ololufẹ ORISUN ati  @iam_smalldoctor , Ẹ Kii ku Oriire naa o!!
 • AworanLoriOrisun TANI O WA NINU AWORAN YII? KINI NNKAN
  2 weeks ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  - TANI O WA NINU AWORAN YII? KINI NNKAN TI Ẹ FẸRAN NIPA RẸ? KINI Ẹ KO FẸRAN NIPA RẸ? -  #Barbie   #Orisun   #OrisunTV 
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related
 • Related
  3 weeks ago by orisuntv Related

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.