Yomi Fabiyi je osere ere theatre ti o odu ti o kin se aimo fun oloko, iyen tunmo si wipe ilumooka ni osere yomi Fabiyi…. Ogbeni Yomi Fabiyi tun je osere ti o tun mu adari ere mo gbogbo awon nkan ti o n se, Awon ere ti Yomi Fabiyi ti se ni Metomi, Ife Iyara Ikawe (Classroom Love) ati beebeelo.

E TUN LE KA: Angeli Yo Si Mi Loju Ala Pe Kin Bere Ise Iranse- Atorise

Ogbeni Yomi Fabiyi ba wa lalejo lori eto Miliki Express Pelu atokun Toyin Oki lai pe yii, won si so oro nipa awon an faani ti awon ti ri ni idi ise theatre yii.. E woo ninu fidio oke yii…

E TUN LE WO:

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.