Ilumooka olorin, Chinagorom Onuoha ti gbogbo eeyan mo si African China ti wan i idi kikorin fun igba ti o pe sugbon opo eeyan pelu awon oniroyin gan o mo nkankan nipa ile aiye re leyin orin tio n ko. Opo o ti e mo boya o ni iyawo tabi omo ni ile. Iforowero kan pelu Sunday scoop ti fi han kedere pe African China tin i Iyawo bi o tie je wipe o fi oruko ati ibi ti won wa pamo…

Ninu Iforowanilenuwo naa, won bi African china nipa awon ebi re sugbon o ko lati so nipa won, won sit un bii nipa iroyin ti o n kan kakaakiri wipe iyawo re ngbe ni oko okun bayii, o so wipe;

“The reason many celebrity marriages fail is because the people involved often forget to leave their celebrity status outside the door. There is a lot of ego play and this undermines relationships. I do not want my wife’s face to be everywhere, then people would begin to say all sorts. I am very certain that most people in the industry don’t know what my wife looks like. We planned it from the onset that my wife and children would stay outside the country, while I would remain here to hustle.”

Won tun bi African China pe Bawo no o se n cope pelu bi iyawo ati omo re se wan i oke okun; o so wipe;
“I simply go over there to meet her anytime I miss her, or feel like seeing her. Though it may not be as often as I want but anytime I’m free, I just travel without letting anybody know my movement.”

Won tun bi African China wipe “ Gege bi ilumooka, o po dandan ki awon orekelewa obirin maa waa kiri, bawo lo se n cope pelu won”, o so wipe;

“None of these girls know that I and my wife live apart; I keep it low key. It’s just that you’re the one that would expose me now, and if I didn’t tell you, you wouldn’t even know. Whenever people ask me, I usually tell them that I’m living with my wife.”

Lori ipo ti o wa ninu Music Industry pelu orin ti o n ko, o so wipe;

“People accepted my last song, Letter to Mr President, with open arms. I only touch on love occasionally, but mostly I sing about things that are affecting people in the land. We need to tackle the issues on ground, or they would always be there. Nobody is going to do it for us. And that is why my fan base is unbeatable. They have been loyal ever since I came on the scene; there’s nothing you can do to chase them away. And that is why I hold my fans in very high esteem.

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

 • IroyinLoriOrisun Omobinrin kan so wipe oun ri oku Tagbo atihellip
  5 hours ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Omo'binrin kan so wipe oun ri oku Tagbo ati wipe o so nkan fun oun Arabirin kan  @digwe  ko si ori ero ayelujara instagram wipe oku ore Davido, oloogbe Tagbo yo si oun o tun so fun oun pe ko ba jise fun eyan kan. Arabirin naa tesiwaju lati so wipe oun ko mo oloogbe Tagbo rii beeni ko mo eyan kankan ti o sunmo. O so wipe oun si ti jise fun eyan ti o ran si. O so wipe o le fun oun lati ri ero ibanisoro eni ti o ran oun si amo oku naa se…
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere AWAMARIDI Starring Yomi Gold Jaiye Kuti Ahellip
  7 hours ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: AWAMARIDI Starring: Yomi Gold Jaiye Kuti A ti n se afihan sinima awamaridi. E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo woo. E ma miss e.  #Orisun   #OrisunTv   #Movies   #Movie   #God   #unquestionable   #Suspense   #Tragedy   #Comedy 
 • IroyinLoriOrisun Awon arakunrin kan yin ibon pa agunbaniro kan nitorihellip
  1 day ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Awon arakunrin kan yin ibon pa agunbaniro kan nitori ko jowo ero ibanisoro e Uwaoma lo ri iya re, Mrs Mary Uwaoma ni ipinle Imo nigbati won paa. Leyin ose kan ti iroyin agunbaniro meji ri sinu omi ni ipile Nassarawa, agunbaniro miran ti o n sin ile baba re ni ipinle Ogun ni awon arakunrin kan yin n'ibon nitori pe ko jowo ero ibanisoro re. Ekene Uwaoma ti o je om'odun meta le l'ogun ti o si je akeeko gboye ni ile-eko giga yi ipinle Imo (I. S. U), Owerri. Gege bi awon oniroyin naa se so, ore…
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere WURAOLA Starring Jaiye Kuti Akin Lewis Idowuhellip
  1 day ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: WURAOLA Starring: Jaiye Kuti Akin Lewis Idowu Hassan A ti n se afihan ere sinima WURAOLA, e lo si ori ero srartimes yin, channel 168 ki e lo wo nkan ti o sele ninu e. E ma miss e.  #OrisunTv   #Orisun   #Movie   #Movies   #Sinima   #SinimaLoriOrisun   #Action   #tragic   #TragiComedy   #Suspense 
 • IroyinLoriOrisun Awon aworan oye ti aya ti o kere julohellip
  1 day ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Awon aworan oye ti aya ti o kere julo ninu awon ayaba Alaafin Oyo ati awon omo re ya Olori ti o kere julo ninu awon ayaba Alaafin ti ilu oyo, Oba Lamidi Adeyemi ti oruko re n je Olori Badirat Olaitan Adeyemi ya aworan ti o lewa pelu awon omo'kunrin re mejeeji, ti won si jo wo aso kanna. Awon aworan naa wa loke. Ekunrere iroyin yii wa ni ori ero ayelujara wa ni  @WWW .ORISUN.TV  #News   #Gist   #Royalty   #Queen   #Beautifuul   #Photos   #OrisunTv   #Orisun 
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere SADE PEPPER Starring Bimbo Oshin A tihellip
  1 day ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: SADE PEPPER Starring: Bimbo Oshin A ti n se afihan ere sinima ti a se afihan re ni ale ana; SADE PEPPER ti o fi ata si arakunrin kan ti o oe ara re ni iranse olorun amo ti o ni ale. E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo woo. E ma miss e.  #Movies   #Movie   #Cinema   #Sinima   #SinimaLoriOrisun   #Action 
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere SADE PEPPER Starring Bimbo Oshin A tihellip
  2 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: SADE PEPPER Starring: Bimbo Oshin A ti n se afihan ere sinima Sade pepper ti e ti n reti, ti e ti n wo ipolowo re, ti e si ti n duro ki a gbe wa fun n yin, oun naa la gbe wa fun n yin bayi; Sade Pepper ti o fi ata ra oju arakunrin kan. E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo wo nkan ti a n soro nipa e fun yin. E ku amojuba.  #OrisunTv   #Orisun   #Movie   #Movies   #Cinema   #sinima   #SinimaLoriOrisun   #Sade  Pepper  #Action   #Suspense   #TragiComedy   #Love   #Betrayal 
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere ILU OSUGBO Starring yinkaquadrifilms E lo sihellip
  2 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: ILU OSUGBO Starring:  @yinkaquadrifilms  E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo wo sinimxa agbelewo ti a gbe wa fun yin. A ti n se afihan re lowolowo. E maa gbadun e.  #Movies   #Movie   #traditional   #OrisunTv   #Orisun   #Sinima   #SinimaLoriOrisun 
 • IroyinLoriOrisun Omo ileiwe eko giga ti ilu Ilorin UNILORIN kuhellip
  2 days ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Omo ile-iwe eko giga ti ilu Ilorin (UNILORIN) ku ni ojo marun si ojo ikeeko gboye re Oloriegbe ti o je akeeko gboye ti Electrical Engineering ku ni ojo aje, osu ti a wa yii. Leyin ti o se aseyori idanwo igba ikeyin re ni ile-iwe naa, iroyin wipe Taofeeqah Oloriegbe ti o je omo'dun meta le l'ogun Oloriegbe fi aye sile ni ojo ayeye ikeeko gboye re ku ojo marun. Oloriegbe ti o setan ni ipo keji ni yara ikeeko Electrical Engineering ku ni ojo aje, ojo 'kerin din l'ogun leyin aisan ranpe. Pelu awon iroyin nipa iku…
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere BABY MI Starring Funsho Adeolu Iya Awerohellip
  2 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: BABY MI Starring: Funsho Adeolu Iya Awero Madam Saje E lo si ori ero startimes yin bayibayi nitori a ti n se afihan ere sinima Baby Mi, nibiti arakunrin kan ti n fi iya agbala kan se aya. E maa gbafun e.  #OrisunTv   #Orisun   #Movies   #Movie   #Sinima   #SinimaLoriOrisun   #Entertainment 
 • IroyinNiSoki Funke Akindele dara ninu oyun Asiwaju ere sinima agbelewohellip
  2 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Funke Akindele dara ninu oyun Asiwaju ere sinima agbelewo "Jenifa Diary' jade sita laipe, ti awo re n dan ti o si se afihan oyun inu re bo ti se n dagba nibi ayeye Glo Lafta Fest 2017 ti won se ni Festac ni ilu Eko. Ekunrere iroyin yii wa ni ori ero ayelujara wa ni  @WWW . ORISUN. TV  #IroyunNiSoki   #IroyinLoriOrisun   #Orisun   #OrisunTv   #News   #Entertainment   #Celebrity   #Couple   #Pregnancy 
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere IBINU Starring odunomoadekola Kemi Afolabi Ibinu tihellip
  2 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: IBINU Starring:  @odunomoadekola  Kemi Afolabi Ibinu ti n ba nkan je, ko si nkan ti ibinu n so di daradara, E lo si ori ero startimes yin channel 168, ki e lo wo nkan ti ibinu ojo kan so ile alayo da. A ti n se afihan ere sinima ohun lowolowo. E maa gbadun e.  #OrisunTv   #Orisun   #Sinima   #SinimaLoriOrisun   #Movies   #Movie   #Ibinu   #Anger   #Angry 
 • Oni ni ojo ibi sekinatolaider okan lara awon aloyinlete Sorosorohellip
  3 days ago by orisuntv Oni ni ojo ibi  @sekinatolaider  okan lara awon aloyinlete Sorosoro Amohuaworan Orisun ,Igba odun odun kan ni ooh
 • IroyinLoriOrisun Idi ti Majid Michel ko ni maa fi enuhellip
  3 days ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Idi ti Majid Michel ko ni maa fi enu ko enu mo ninu sinima agbelewo Gbaju-gbaja osere 'kunrin ti o di ajihinrere, Majid Michel ti so wipe oun ko gba ere fifi enu ko enu mo ninu ere sinima mo, ipinu ti o se ma ranlowo lati mu ihinrere losi opin aye. O fi ipinu titun yii han nibi iforo jomitoro oro lori Bryte FM, saaju aworan ere sinima 'Adam The Eve' ni Koforidua lojo abameta, ojo 'kerinla osu 'kewa.  #IroyinLoriOrisun   #IroyinNiSoki   #News   #Lifestyle   #Entertainment   #Gist   #OrisunTv   #Orisun   #Celebrity   #Actor   #Star 
 • IroyinNiSoki Idi ti Olori Wuraola se maa n wo asohellip
  3 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Idi ti Olori Wuraola se maa n wo aso funfun nikan maa n da eeyan l'orun. Olori Wuraola Ogunwusi, wife of the Ooni of Ife Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) speaks to Punch about her pet projects and life in the palace. Olori Wuraola Ogunwusi, aya oba alayeluwa Ooni ti ilu Ife Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) soro fun awon oniroyin nipa ise re ati igbesi aye re laafin. Fun ekun rere iroyin yii, e kan siwa lori ero ayelujara wa ni WWW.ORISUN.TV  #IroyinLoriOrisun   #Iroyin   #News   #HotNews   #Gist   #Lifestyle   #OtisunTv   #Orisun   #Marriage   #OoniOfIfe 
 • IroyinNiSoki Idi ti Olori Wuraola se maa n wo asohellip
  3 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Idi ti Olori Wuraola se maa n wo aso funfun nikan maa n da eeyan l'orun. Olori Wuraola Ogunwusi, wife of the Ooni of Ife Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) speaks to Punch about her pet projects and life in the palace. Olori Wuraola Ogunwusi, aya oba alayeluwa Ooni ti ilu Ife Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) soro fun awon punch nipa ise re ati igbesi aye re laafin. Fun ekun rere iroyin yii, e kan siwa lori ero ayelujara wa ni WWW.ORISUN.TV  #IroyinLoriOrisun   #Iroyin   #News   #HotNews   #Gist   #Lifestyle   #OtisunTv   #Orisun   #Marriage   #OoniOfIfe 
 • IroyunNiSoki Davido ni oro fun awon ti o fi esunhellip
  3 days ago by orisuntv  #IroyunNiSoki  Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan Davido ti se afihan re wipe oun ko ninikun sinu kankan mo so enikeni ti o l'ero wipe oun niowo ninu iku Tagbo. Fun ekunrere iroyin yii, e lo si ori ero ayelujara wa ni WWW.OTISUN.TV  #IroyinLoriOrisun   #Iroyin   #Orisun   #OrisunTv   #Entertainment   #Gist   #HotNews   #Celebrity   #Lifestyle 
 • SinimaLoriOrisun Akole Ere ANGELA MAHOO Starring Aishat Abimbola Habibat Jinadhellip
  4 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  Akole Ere: ANGELA MAHOO Starring: Aishat Abimbola Habibat Jinad A ti n se afihan ere sinima agbelewo Angela Mahoo ti e ti n reti; obirin bii okunrin, obinrin ti o n fo okunrin leti to n daku. E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo wo o. E ma miss e.  #OrisunTv  # Orisun  #Entertaining   #Entertainment   #Movies   #Movie   #Strong   #Mighty   #Action   #Comedy   #TragiComedy 
 • IroyinLoriOrisun Bi won se fi esun kan Bidemi Kosoko wipehellip
  4 days ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Bi won se fi esun kan Bidemi Kosoko wipe o n ba oko oloko sun nitori egberun lona egberun naira Won tun ti fi esun agbere kan okan ninu awon omo agba gbaju-gbja osere 'kunrin Jide Kosoko ti oun naa je gbaju-gbaja osere 'binrin ninu ise tiata, Bidemi Kosoko. Arabinrin kan Mamaking111111111 pariwo pe Bidemi lori ero abanidore wipe o n ba oko oun sun ninu ile oko e fun ose kan nigbati oun wa ni ilu Dubai fun bi ose meji seyin. Gege bi obinrin naa se so, osere 'binrin naa ti n Yo oko oun lenu leyin…
 • SinimaLoriOrisun AkoleEre AGBADA ESAN Starring Damola Olatunji Funke Etti Bidemihellip
  4 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun   #AkoleEre : AGBADA ESAN Starring: Damola Olatunji Funke Etti Bidemi Kosoko Afeez Eniola Omokunrin kan ti o ti kawe gboye fun omo ile-iwe ti o je omo baba onile re ni oyun, ko si gbaa; omobinrin naa ti tori itiju lo se oyun ohun, amo boya oku tabi o ye iyen ni ki e lo se awari re. A ti n se afihan re lowolowo. E lo si ori ero startimes yin, channel 168 ki e lo woo.  #Sinima   #SinimaLoriOrisun   #Movies   #Movie   #Action   #Death   #Pregnancy   #SayNoToAbortion   #OrisunTv   #Orisun   #Suspense   #Revenge   #Regret 

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.