Piracy je nkan ti o n ba inu awon ti o wa ni Entertainment Industry je latari pe awon eni ibi won yi o je ki won jere ise owo won. Oga agba Ajo NFVCB ti o je alejo wa lori Eto baba Eto

Piracy je nkan ti o n ba inu awon ti o wa ni Entertainment Industry je latari pe awon eni ibi won yi o je ki won jere ise owo won. Oga agba Ajo NFVCB ti o je alejo wa lori Eto baba Eto so wipe ewon ni eni ti o ba n se piracy ati gbogbo ebi re yoo lo. Nnkan eyokan ti alejo wa so koni eyi. O so nnkan miran ti eti yin yoo fe gbo….

E TUN LE WO: Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

E wo ba yii>>>>

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.