Gospel artiste, Deacon dorcas awolumate aka ibi giga ti won je alase gospel band ti won pe ni "Dorcas Awolumate Music Ministry and Sounds of Victory Band"

Gospel artiste, Deacon dorcas awolumate aka ibi giga ti won je alase gospel band ti won pe ni “Dorcas Awolumate Music Ministry and Sounds of Victory Band”ni won ba wa lalejo lori eto Miliki Express pelu Lara Olubo. Lori eto yi won ba wa soro lori bi won ti ma n ri isipaya fun awon orin won ati idi ti won fi so akori orin won ni Ibi Giga ati opo iyanu ti olorun ti se ni ile aye won….

E TUN LE WO: Ti Kennis Music Ba Fe Olorin Mi Maa Fun Won- jaywon

E wo ba yii>>>>

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.