A mo ki laa se ti oko ba wa ni ori express tabi ona ti o jin si Mechanic? Opo eyan ni o mo ogbon ti won le da si oko ti o ba yonu.

Moto tabi oko je nkan ti o le daku ni igbakugba lai fi ami han pe ohun yoo da ise sile, eyi ti o je pe a le pe atun oko se iyen Mechanic pe ki o wa tun se. A mo ki laa se ti oko ba wa ni ori express tabi ona ti o jin si Mechanic? Opo eyan ni o mo ogbon ti won le da si oko ti o ba yonu. Lori eto Bosenlo, a o soro nipa bi a se le Overheating ninu oko ati nkan ti a le se si.

E TUN LE WO:#Bosenlo: Nkan Ti A Le Se Ti Tyre Moto Ba Baje

E wo ba yii>>

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.