Orisun ni agba, awa ni Oga. Ki ni idi ti a fi n so be? A ma n wi be nitori pe bi a ti n se nkan wa o yato si bi gbogbo ile ise se n se nkan won.

Orisun ni agba, awa ni Oga. Ki ni idi ti a fi n so be? A ma n wi be nitori pe bi a ti n se nkan wa o yato si bi gbogbo ile ise se n se nkan won. Oga agba ile ise Orisun eyi ti o n se alakoso fun ile ise telifisan awon yibo ti won npe ni Isimbido da eto weje-wemu sile ni agbegbe ileese naa lati mo riri awon atokun eto wa. Ibi ayeye yi ni oga wa Kwame ti ki ijo mole pelu gbogbo awon atokun wa…

E TUN LE WO: Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

E wo ni bi yii>>

 

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

Ipolowo

BOURNVITA
BOURNVITA @50

Gbajumo Wa

FUNKE AKINDELE-BELLO
Akindele Olufunke Ayotunde (popularly known as Funke Akindele, born August 24, 1976 in Ikorodu, Lagos State, Nigeria) is a Nigerian actress. She came to limelight after featuring in popular United Nations Population Fund (UNFPA) sponsored sitcom; I Need to Know, which ran from 1998 to 2002.

Awon Eto Wa Lori Akiiyin Losu Yii

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.