Miliki tabi Faaji je nkan ti awon eniyan paapaa julo awon okunrin o ki fin para rara. opo igba le ma ri ti won ma so wipe awon o le se lai ma se faaji

Faaji tabi Miliki je nkan ti awon eniyan paapaa julo awon okunrin o ki fin para rara. opo igba le ma ri ti won ma so wipe awon o le se lai ma se faaji tabi ki awon ma miliki. Ayinke ati Busola yannana oro yi lori eto miliki express ti won si jade lati lo bi awon eniyan pe ki ni anfaani miliki/faaji. ibi ni won ti pade osere Baba Tee ati Dejo Tunfulu ti won si so ero won lori akori yi…

E TUN LE WO:Idi Ti Mo Fi Ko Orin Banuso- Jaywon

E wo ba yii>>>>

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.