Ogbeni Evans ti aye n so wipe ki won da sile leyin ti won ti mu fun esun ijinigbe ati opolopo ise ibi ti o ti gbe se si wa lewon. Lana ti o je Ojo Aje, ni a rii gbo wipe Otito miran ti jade nipa Isele naa.

Ogbeni Evans ti aye n so wipe ki won da sile leyin ti won ti mu fun esun ijinigbe ati opolopo ise ibi ti o ti gbe se si wa lewon. Lana ti o je Ojo Aje, ni a rii gbo wipe Otito miran ti jade nipa Isele naa.

Chukwuemeka Okoye ti o je egbon iyawo evans ti fidi otito mule nipa ibasepo ti o wa laarin oun ati idile awon aburo re Uchenna Precious Onwuamadike ti o je iyawo Ogbontarigi Oloro Ajinigbe nni Evans. Arakunrin Chukwuemeka so wipe leyin ti aburo re ti se igbeyawo, oun ko fi ese tabi oju kan aburo oun.

E TUN LE KA:

Gege bi iroyin ti o te wa leti, Okoye so wipe, kosi ibasepo ti o dan monran laarin ebi Evans ati ebi Okoye. O so wipe titi di igbati baba awon ti fi aye sile ni odun 2014, Uchenna ti o je aburo re ati oko re ko tile yoju fun ayeye ikehin baba awon. Okoye ti o je agbe ni agbegbe Awo Oraifite ni ijoba ibile Ekwusigo ni ipinle Anambra. Beeni o tun salaye wipe, Bi o ti buru to, Awon kii soro lori ero alagbeka, beeni oun ko mo wipe aburo oun ti bi omo marun-un.

Iwadi si n tesiwaju lori Ogbeni Evans ati awon iwa buruku ti o ti se seyin. E ma gbagbe lati maa wo orisun.tv bi iroyin naa se n lo.

E LE WO FIDIO YII:

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

E Tumo Gbogbo Oro

Ipolowo

BOURNVITA
BOURNVITA @50

Gbajumo Wa

mide funmi-martins
Mide Funmi Martins (born April 12) is a Nigerian film actress and producer, popularly known for Omo oku òrun (2004), Erù elérù (2003) and Arewà (2003). She is the daughter of late Funmi Martins. Mide is married to a popular Nollywood actor and producer Afeez Owo.

BI E TI LE RI OKO GIDI ATI PIPE NI ILE OKO

E Bawa Soro Lori Twitter

Instagram Slider

 • AkiiyinO Bi Toyin e na w yii Lj kan laiphellip
  5 hours ago by orisuntv  #AkiiyinO  Bi Toyin ṣe na ọwọ yii.... Lọjọ kan, laipẹ laijina AYỌ YIN YOO DE OOOO... Ẹ ṣe aamin
 • SinimaLoriOrisun AKOLE ERE TOJU TIYE Starring Yinka Quadri Fausat Balogunhellip
  20 hours ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  AKOLE ERE: TOJU TIYE Starring: Yinka Quadri, Fausat Balogun, Lukman Raji. E wo lago mejo ni channel 168.
 • EtoTonLo BoSenLO NKAN TI O N SELE NINU ERE IDARAYAhellip
  23 hours ago by orisuntv  #EtoTonLo   #BoSenLO  NKAN TI O N SELE NINU ERE IDARAYA. Ajo CAF ti n se eto bi won se ma gba AFCON 2019. Won n se opolopo ipade lati gbegba oroke ju ti ateyin wa lo. E wo lago marun ni Channel 168. Be ni esi ni anfani lati wo ni WWW.YOUTUBE.COM/orisuntv.
 • EtoTonLo AkiyinO BI A SE LE MU INU IYAWO WAhellip
  1 day ago by orisuntv  #EtoTonLo   #AkiyinO  BI A SE LE MU INU IYAWO WA DUN Kini ohun ti a n se lati fi mu inu ololufe wa dun. Nje a mo wipe opolopo obinrin lo feran ki oko oun dana fun oun; bi oti e je leekan tabi ki o maa mu oun jade? E wo eto yii lago merin ni Channel 168. Fun eyin ti e ko ni ni anfani lati wo eto yii e ni ore-ofe lati wo ni WWW.YOUTUBE.COM/orisuntv.
 • EtoTonLo MilikiExpress LILO OPIN OSE WA Atokun wa so irufehellip
  1 day ago by orisuntv  #EtoTonLo   #MilikiExpress  LILO OPIN OSE WA Atokun wa so irufe ona meta ti a se le lo opin ose wa. Se ode owanbe ni e ma n lo ni abi ode ikomo? E ba wa pade lori eto Toni Pelu alejo wa Esther Igbekele lati fi mo bi won se n lo opin ose won? E wo eto toni lago kan ni channel 168.
 • SinimaLoriOrisun AKOLE ERE IFA Starring Dele Odule Antha olaniyan Erehellip
  1 day ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  AKOLE ERE: IFA Starring: Dele Odule, Antha olaniyan Ere naa lowolowo ni channel 168 orisuntv.
 • AworanLoriOrisun Eyin ololufe wa Lori orisun ninu awonran yii ehellip
  1 day ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  Eyin ololufe wa Lori orisun ninu awonran yii e wo le feran ju lati maa fi ran aso si ara wa?
 • SinimaLoriOrisun AKOLE ERE AKANNI Starring jideprince Baba suwe Olaiya Ehellip
  4 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  AKOLE ERE: AKANNI Starring:  @jideprince , Baba suwe, Olaiya. E wo ere yi lagogo mejọ oni. ... KINI O MAA N GBẸYIN OGUN OWO??
 • EtoTonLo Ojuri ETO ISUNA NINU ILE Awon Alejo wa sorohellip
  4 days ago by orisuntv  #EtoTonLo   #Ojuri  ETO ISUNA NINU ILE Awon Alejo wa soro lori bi eto isuna se le so ile wa de ile alayo ati wipe se okunrin nikan ni eto isuna inu ile to si ni abi Pelu obinrin na. E wo to yi lowolowo ni Channel 168. Eyin ti e ko si ni anfani bayi e WO ni WWW.YOUTUBE.COM/orisuntv.
 • EtoTonLo BoSenLo PATAKI GBIGBA ABERE AJESARA Atokun wa Pelu Alejohellip
  4 days ago by orisuntv  #EtoTonLo   #BoSenLo  PATAKI GBIGBA ABERE AJESARA Atokun wa Pelu Alejo re n soro lori Iwulo abere ajesara fun awon omo owo titi de omo odun mewa. E wo eto yi bayi ni channel 168 orisuntv. Fun eyin ti e ko si ni ina manamana e ni anfani Lati wo ni WWW.YOUTUBE.COM/orisuntv.
 • EtoTonLo MILIKIEXPRESS ORO ISITI FUN A WON ODO NI ILEIWEhellip
  4 days ago by orisuntv EtoTonLo  #MILIKIEXPRESS  ORO ISITI FUN A WON ODO NI ILE-IWE GIGA  @Ayinkedayokujore  ati  @Officialmadiva  Oro Isiti Fun Awon Odo Wa Ni Ile-Iwe Giga Papa Ju Lo Awon Olomoge Wa ti Won Lero Wipe AWon Ti Gba Ominira Nitori Wipe Won ko Sii Pelu AWon Obi won. Awon Atokun Wa Soro Lori Aafani Ati Alebu Ti O Wa Ninu kii Omo Obirin ma Gbe Pelu Omo Okunrin Ti Won Ko Ti Fe Ara Won Si Ile. Ti Aba Si Wo Oro Yii O Wopo Larin Awon Omo Ile-Iwe wa...Eyin ti telifisan yin ko si Pelu yin tabi ko si INA manamana,…
 • SinimaLoriOrisun AKOLE ERE POTATO Ore meji ti won sa gbogbohellip
  4 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  AKOLE ERE: POTATO Ore meji ti won sa gbogbo IPA won Lati fi lowo sugbon igbeyin won ninu ere yii......hmmmm E lo woo baibai Lori Orisun Starring:  @adeolufunsho  CH 168.  @startimesng 
 • AworanLoriOrisun Oibajo plu Aya r nibi idup lana j Aiku
  5 days ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  Oṣibajo pẹlu Aya rẹ nibi idupẹ lana Ọjọ Aiku
 • SinimaLoriOrisun AKOLE Orogun Oko Starring TAIWO HASSAN deleodule E ohellip
  5 days ago by orisuntv  #SinimaLoriOrisun  AKOLE: Orogun Oko Starring: TAIWO HASSAN,  @deleodule  E o rii wo nii Aago Mejo Ale Oni. Tani O Ti woo ri?  #OrisunTv 
 • IroyinLoriOrisun Iroyin Jakejado Nigeria ati agbaye ni o n lohellip
  5 days ago by orisuntv  #IroyinLoriOrisun  Iroyin Jakejado Nigeria ati agbaye ni o n lo lori Orisun.... E wo bi won sese ayeye ojo ibi Iya Afin Osinbajo ati beebeelo..... Fun eyin ti e ko rii wo bayi e wo ni WWW.YOUTUBE.COM/orisuntv

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.