AKOJOPO IROYIN

E Tumo Gbogbo Oro

Ipolowo

BOURNVITA
BOURNVITA @50

Gbajumo Wa

mide funmi-martins
Mide Funmi Martins (born April 12) is a Nigerian film actress and producer, popularly known for Omo oku òrun (2004), Erù elérù (2003) and Arewà (2003). She is the daughter of late Funmi Martins. Mide is married to a popular Nollywood actor and producer Afeez Owo.

BI E TI LE RI OKO GIDI ATI PIPE NI ILE OKO

E Bawa Soro Lori Twitter

Instagram Slider

 • IroyinNiSoki Emi naa wa lara awn ti yoo da ogohellip
  2 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Emi naa wa lara awọn ti yoo da ogo PDP pada oooo!!! - Ọgbẹni Pat Utomi
 • Eto isinku oloogbe Dr Adesina Samuel Adesanya ti gbogbo wahellip
  4 days ago by orisuntv Eto isinku oloogbe Dr Adesina Samuel Adesanya ti gbogbo wa mo si Pastor Ajidara......Yoo waye ni 24th Titi Di Ojo 27th Osu yii
 • Late Moji Olaiyas remains in Canada Via Yorubamoviegist
  4 days ago by orisuntv Late Moji Olaiya's remains in Canada.... Via: Yorubamoviegist
 • IroyinNiSoki Gomina AMBDE wa ni Abule gba nibi ti ahellip
  6 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Gomina AMBỌDE wa ni Abule Ẹgba nibi ti a ti n ṣi Oju Ọna tuntun ti Oke Odo ni Abuke Ẹgba
 • IroyinNiSoki Wn ti f i oju na naa oooo Gbogbohellip
  6 days ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Wọn ti fẹ Ṣi oju Ọna naa oooo Gbogbo Ẹyin ara OKE odo ni Abule Ẹgba
 • IroyinNiSoki Ijamba k ti l si Malaika ooooo kunrr Iroyinhellip
  1 week ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Ijamba Ọkọ ti ṣẹlẹ si Malaika ooooo... Ẹkunrẹrẹ Iroyin bi o ti ṣẹlẹ naa wa ni www.orisun.tv
 • AkiiyinO KU IMURA AW oooooo mi wa a e puphellip
  1 week ago by orisuntv  #AkiiyinO  ẸKU IMURA AWẸ oooooo Ẹmi wa a ṣe pupọ rẹ laye ooo. Agbara ati laada gidi ni a o ri gba nibẹ oooo
 • IroyinNiSoki Awn m ibk ti l pade awn obi wnhellip
  1 week ago by orisuntv  #IroyinNiSoki  Awọn Ọmọ Ṣibọk ti lọ pade awọn obi wọn lati Ọjọ Ẹti to kọja oooo... ẸYIN ọmọ Nigeria Ẹ ma foya. Oṣibajọ ko ṣọ bẹẹ.. Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa ni www.orisun.tv
 • OjoIbiLoriOrisun NNKAN MWA WO NI M NIPA REMI SURUTU??hellip
  1 week ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  NNKAN MẸWA WO NI Ẹ MỌ NIPA REMI SURUTU?? Lọjọ Ibi rẹ yii ooo. Ayọ ati alaafia ni a n bẹ Edumare ki o fun wọn ninu aiku baalẹ Ọrọ cc  @therealremisurutu 
 • AworanLoriOrisun AY ATI IDUNNU NI O FI LO OPINhellip
  2 weeks ago by orisuntv  #AworanLoriOrisun  AYỌ ATI IDUNNU NI Ẹ O FI LO OPIN ỌSẸ Yiii ooo
 • BosenloSports EreIdaraya Bi o e l nibi Ere blu tihellip
  2 weeks ago by orisuntv  #BosenloSports   #EreIdaraya  Bi o ṣe lọ nibi Ere bọọlu ti a gba sẹyin ati iroyin nipa Awọn ere idaraya miran. Lori orisun ni oooo
 • OjoIbiLoriOrisun HBD feenatgold Oluwa A mu lara da ooo
  2 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  HBD  @feenat_gold  Oluwa A mu ẹ lara da ooo
 • OjoIbiLoriOrisun HBD anjysworldprd Maa dagba ninu Alaafia ati Ilera arahellip
  2 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  HBD  @anjysworldprd  Maa dagba ninu Alaafia ati Ilera ara ooo. A nifẹẹrẹ ni Ileeṣe Orisun
 • OjoIbiLoriOrisun Nnkan lg ni Obinrin j oooo yin kunrin hellip
  2 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  Nnkan Ẹlẹgẹ ni Obinrin jẹ oooo. Ẹyin Ọkunrin, Ẹ ṣekẹ Aya yin ki ẹ si ranti Ọjọ ibi wọn. O maa n mu Inu wọn dun. HBD  @misturaasunramu 
 • OjoIbiLoriOrisun HBD babatee1
  2 weeks ago by orisuntv  #OjoIbiLoriOrisun  HBD  @babatee .1

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.